No. 10 · Orin Idande · Orin AduraẸnyin ara oke SioniLyrics1Ẹnyin ara oke Sioni Ẹ wo iyanu T'ọba giji Holy Center Se fun ọmọ rẹ.2Bi mo si ti nrin lọ lọna Mo pade Amatẹkun O na ọwọ rẹ lati mu mi Adaba gbe mi fo.3O joko o gbe oju soke O ya ahọn rẹ si mi Adaba ti gbe mi soke Holy Center mi.4Lala lo ngbọro fere mi Ati iro orin mi O sumọ eti ile mi Lati bu mi şan.5Ọta fara han bi ọrẹ Ẹ wo lemi o şe ? Ọta fara han bi ọrẹ Gba mi o Baba6Mo pe ẹnyin Ologun Ọrun Mo pe ẹlẹda mi Ki o gbami lọwọ Amatẹkun Amọni şe ni.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌSimilar hymns32Rabibon jo sannu fun mi1998 · Orin Idande154Mase binu silu Eri mo1964 · Orin Idande220Eri ti mo ri ni mo nlo Baba1955 · Orin Idande11Gbogbo ẹnyin Nasiry igbani1964 · Orin Idande Previous9 · Fi ara re fun OlorunNext 11 · Gbogbo ẹnyin Nasiry igbani