Before you read

No. 116 · Orin Adura

Bi iṣan omi ti mbo bebe odo

Lyrics

Chorus

Ẹbẹ mo mbẹ Ọlọrun mi Pe bi iṣan omi ti nkọja lọ Bẹni ki ẹṣẹ mi ṣan kọja lọ Bi igbati ikuku mba ọjọ lọ.

Chorus

Ẹbẹ mo mbẹ Ọlọrun mi, etc.

Chorus

Ẹbẹ mo mbẹ Ọlọrun mi, etc.

Chorus

Ẹbẹ mo mbẹ Ọlọrun mi Pe bi iṣan omi ti nkọja lọ Bẹni ki ẹṣẹ mi ṣan kọja lọ Bi igbati ikuku mba ọjọ lọ.

Amin.

About this hymn

Written by
Prophet Mennary
Year
1956

ORIN MIMỌ SAINARY ALORE FUN IRONUPIWADA Psalm 51 : 1-29

Similar hymns