No. 125 · Orin Ekun Alore · Orin IdandeKini mo șe yin, ti ẹ fi npokiki mi ? (2 times)Lyrics1Kini mo șe yin, ti ẹ fi npokiki mi ? (2 times) Ti ẹ fi nparada, ti ẹ ndi ẹranko Lati ba mi ja.2Kini mo șe yin, ti ẹ fi ndọdẹ ọkan mi ? (2 times) Ti ẹ fi nparada ti ẹ ndi ẹranko Lati ba mi ja.3Kini mo șe yin, ti ẹ fi nlepa ẹmi mi ? (2 times) Ti ẹ fi nparada ti ẹ ndi ẹranko Ti ẹ mba ẹmi mi ja.4Kini mo șe yin, ti ẹ fi mbere ẹjẹ mi Kini mo șe yin, ti ẹ fi nwa iku fun mi Ti ẹ fi nparada, ti ẹ ndi ẹranko Lati ba mi ja.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns120Adaba ẹri mi o, nibo lore o ?Orin Ekun Alore147Olorun Elisha iwo ni OlorunOrin Ekun Alore162Mo nikan wa ninu Ogba1959 · Orin Ekun Alore95Wo ẹkun mi o, Rakeli mi oOrin Ekun Alore Previous124 · Itanna nru eweNext 126 · Nitori Oluwa mo fi ile mi silẹ