No. 144 · Orin Iyin ati Ọpẹ · Orin IsegunHalleluyah ayo mi kunLyrics1Halleluyah ayo mi kun Nigbati Kristi pe mi Kuro ninu okunkun aiye Halleluya ayo mi kun2Esu npon awon baba wa loju O mu wọn sin Olorun ajeji O mu won teriba fun igi Nwon fokuro nse woli3Gbati Mose. sunmole O fowe mba ijo soro Pe Olorun yio ma soro A o sin gbo nilu Ilaje4Ni odun 1948 Lene pa ago ijosin fun Olorun O ko egbegberun enia Kuro labę ijosin esu5Halliluya ayo mi kun Gbati mo kuro loko eru Mo pada silu Ugbo-nla Halliluyah, Halliluyah, Halliluyah.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryEXMINARY ALORE C&S SAINARY ALORE JESUSimilar hymns138Olorun OlodumareOrin Iyin ati Ọpẹ110Iwọ nikan loju mi jọ loju Oluwa (2ce.)Orin Iyin ati Ọpẹ137Olugbala mo dupeOrin Iyin ati Ọpẹ112Oju Kristi ni oju Adaba miOrin Iyin ati Ọpẹ Previous143 · Faso alore re Ologo wo mi oNext 145 · Okan mi nse aferi orun