No. 151 · Orin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ · Orin AduraOju Mennah mi, oju Adaba miLyrics1Oju Mennah mi oju adaba mi Ti mo nwo loke Eri to mi Oju ti are ki mu Ti nfi igba gbogbo ntan imole2Bi gbogbo aiye ko yin O baba Emi tise ileri Igbagbo Re Nipa Oju Mimo Re ti mo ri Mo mo pe oju ife ni.3E ji dide enyin koriko E fi imole han enyin itana Gbogbo ikuku e da kuro Ki orun ati osupa tan imole4Imole Kristi ran si mi Fi iran Re kun inu ati okan mi Ki nle fi Oju Olorun han Fun gbogbo awon ti ko ri5Iwo itansan elewa Iwo Oju adaba eri Irisi Re wun mi pupo Olorun mi Olufe mi.6Gbogbo ewa aiye yio baje Sugbon ewa Re ki baje Pin fun mi ninu ewa Re Ki nle wa ninu ewa pipe.7Iwo Imole iyebiye To se amona awon ara Igbani Jo tan Imole Ogo Re si mi Se mi - pe ninu ewa re.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO Sainary AloreSimilar hymns2Bi o se da mi si Oluwa Orin Adura3Iwo oro Olorun - Ogbon ati oke waOrin Ikede Oro Olorun4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura9Elo Hermar - Elo HermarOrin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ Previous150 · Mennah rasion manna alauNext 152 · Ninu aginju awe mo wa yi