No. 21Mo fi ope fun OlorunLyrics1Mo fi ope fun Olorun To so mi loru yi Tỉ o mu ki oju mi ri Imole nla orun2Gba mi lowo ajakale arun Ati lowo otutu Gba mi lowo oso ati aje Ki o si dá abo bo mi3Gba mi lowo Angeli esu To nrin nigba oru Gba mi lowo eke Woli Ti nrin losan gangan4Baba so mi nigba oru yi So mi nigba osan So mi niwakati gbogbo Ki esu ma ba pa mi5Oluwa mi mo fe lo sun Ni wakati oru yı So mi bi awon oluso aguntan Ti nso aguntan won6Modupe lowo Jehovah To nso mi lojojo Ijoba agbara ati ogo Fun o loke orunAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO ADURA OWURO ATIALE Previous20 · Edumare tun aiye mi seNext 22 · Kristi jọba Aleluya