No. 219Nigbatı mo ri ogo orun tanLyrics1Nigotı mo ri ogo orun tan Ti mo si wo ogo aye Ko si ibi isimi kan fun mi Bi Adaba Noah mo nfo Lati ijosin kan de ikeji Boya emi yo ri ibi isimi mi2Ni gbogbo ijosin ti mo de Mo ri oloto lori oye Aje si tun wa lori ite Mo ri okunkun ati imole Ninu ijosin aye yi Emi ko le ba won gbe po3Ile ti a pe ni ti Olorun Mo ri oloto lori oye Aje si tun wa lori ite Mo ri okunkun ati imole Ninu ijosin aye yi Emi ko le ba won gbe po.4Ile adura Oluwa Aje ko le wa lori aga Oloto yio wa lori ite Okunkun ko le si nibe Imole nikan lo ngbe ibe Nibe ni emi mi fa si5Emi Oluwa nso fun mi Pe aje ko le gbe odo on Beni eke ko le gbe odo on Ninu ijosin aiye yi Aje nse idajo bi oloto Emi mi ko papo mo won6Mo wo Gogbo josin aye Emi ko ri amoye orun Ariran aye ni mori Emi mi ko papo mo won Tori won ko mo ohun orun Won ko ledidi igbagboAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneNIGBATI IMOLE OWURO Previous218 · Olorun Metalokan awa omo reNext 220 · Baba omo emi mimo Gbo adura ti mo ngba yi