No. 229Idamu pupo lo ba mıLyrics1Idamu pupo lo ba mı Aiye nbu mi lona gbogbo Olorun ebe ni mo be Majeki nle si oro re so2Gbati mo ri oro e re gba Lati so otito fun aiye Awon ti o korira mi Si ju irun ori mi lo.3Ebi Baba ko mi sile Nitori oro ihinrere Ebi iya ko mi sile Gbati mo gbe agbelebu4Ona wo lemi o rin si? Gbati ara aiye ko mi sile Baba ma jeki npadanu aiye Kin nle jogun l'ajinde re5Alabaro jina si mi Emi ko ni olutunu Baba jo se alagbawi mi Mase jeki emi rufin re6Gbogbo ara ile mi nbu mi Nitori oro edidi re Gbogbo elegbe mi si ko mi Nitori oro Jesu mi7Gbati gbogbo ara aiye ko mi Mo gbe gbogbo ara mi le o Toju mi labe iye apa re Mase jeki emi ri o si moAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneMA GESIN LO Previous228 · Awon Kan nrope Olorun ko si oNext 230 · Lodun keta sehin, L'Oluwa ti pe