No. 233A ko ni ibugbe kan nihinLyrics1A ko ni ibugbe kan nihin Ti ao ko isura wa si Ko ye fun awa onigbagbo Pe ki aferan aiye ju Olorun lo2Ise awon Woli igbani Nwon nso asotele Gege bi Oloruin ti ran won Nwon nsoro ofin Jesu fun wa3Ise awon Aposteli igbani Nwon niwasu oro Kristi Nwon si nwo awon alaisan Nwon nsoro ite Olorun4Gbogbo Woli ti Olorun yan Ati enyin Aposteli Ati gbogbo egbe akorin E ranti elegbe nyin igbani5Mo be gbogbo enyin elegbe mi Lokunrin ati Obirin Pe ki a ranti oro Jesu Ti o ntoju wa lojojumo.6Bi a ko tile mona rara Ti a nse ifekufe Ebi wa ko nipo pupo Ju igbati a mona, ti a kose ifeAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous232 · Gbogobo odo omode bi emi