No. 236Lodun keta sehin, L'Oluwa ti peLyrics1Lodun keta sehin L'Oluwa ti pe O si fun mi lase Lati ma gbadura.2Mo gbo ohun Oluwa pe Ki npe gbogbo alaisan Ati awon ti ko bi Ki ngbadura fun won3Mo pe enia meji Mo se eketa fun won A nse ise Oluwa Alaisan nri iwosan4Lodun meji gbako La se ise Oluwa Agan si di Olomo Alaisan ri iwoswan5Esu ndena pupo Lodo adura wa O nde gbogbo obinrin Kin won ma le bimo6Bi esu ti gbogun to Awa ri eri gba A si ri oro gba Edidi otito.7Mo dupe lowo re Toju mi labe iye apa re Mase jeki emi ri o si mo Olorun Oluwa Alaisan ti mo wo Ko si enikan to ku.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneOLORUN AWA NFE Previous235 · Idamu pupo lo ba mıNext 237 · Wa, wa, emi mimo