No. 242Ohun ti ndun ni aginjuLyrics1Ohun ti ndun ni aginju Ohun Alore ni Gbo bi ohun na tin dun rara wipe Eronu piwada Ohun na ko ha ndún pe ọ? Ipe na ko kan o?2Ijoba ku si dede Ijoba Olorun Awon to ti foso won Nikan ni yo gunwa Ese ti o ko fi na ni? Ohun Alore yi Tindun leti re, tantan pe Eronu piwada3Abana pelu farpar Le je odo mimo Sugbon ase iwenu mo Jordani nikan lo ni Ju ero re si apa kan Se ase Oluwa Wa simi ni adagun yi We ki o si di mimo4Kilohun ti iba da o ro? Awawi kan ko si Wo ile Adura gbo oro Olorun Ohun gbogbo se tan O pe pupo lori ikede Eronu piwada Elese gbo ohun Alore Si ronu Piwada.AminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous241 · Bi Oluwa ti pe miNext 243 · Mo dupe lowo re Jesu omo Baba