No. 244A o se ise omo Olorun ni waLyrics1A o se ise omo Olorun ni wa Awon kan nwipe, akoko ise koto Jeka se ise Jesu niwa2Ikore po alagbase ko to Jeka se ise ki alagbase ba le wa A o se ise omo Kristi lawa3Gbogbowani Olorunnpase fun Pe kase ise lakoko owuro yi Jeka se ise kale jere Jesu4A ọ Kede orọ Olorun wa To pe wa kuro ninu okunkun A o ròhin Isę iyanu Baba5Jeka se ise nitori orun mbo Nigbati enikan ko le se ise Jeka se ise nigabti a wa laye.6Lowuro yi lo yeki ase ise wa Igba kan mbo ti iku yio mu wa lo Ti awa yio ma reti idajo waAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous243 · Mo dupe lowo re Jesu omo BabaNext 245 · Ki awa to pari eko wa Awa fi iyin fun o