No. 246Ko mi Oluwa Olorun miLyrics1Ko mi Oluwa Olorun mi Ki nle mo ibere ojo aiye mi Jeki nlemo igba opin mi Ki nmo igbati ngo se alaisi.2Wo gbogbo awon omo eke Ti nse ipade lojojumo Nwon nfe ke igi ororo lule Nwon fe be ajara lule.3Ranti gbogbo ojo to nro Ti ile fi nmu o lojojumo Wo gbogbo awon igi nla Ti ina kekere njo lule.4Oluwa mi Olorun mi Wo ojo to nro lemi lori Wo iri to nse, si irun ori mi Jek'o da ororo sori mi.5Baba wo gbogbo omo oso Ti nse ipade lojojumo Nwon si nfo eso ajara ka Nwon ko fe ki oro gbinle.6Olorun jeki Keferi Ati awon ti nbo orisa Le sare wa si imole re Jeki oro re le gbinle.7Olorun mi mo mbe o ni Ki nle mo igbati emi o lo Lori ile aiye osi yi Ki nle mo igbati ti emi o ku.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneWA SODO MI OLUWA MI Previous245 · Ki awa to pari eko wa Awa fi iyin fun oNext 247 · Oba mimo jowo dakun ye o