No. 283Gbo, gbo adura mi; Olorun Oba OloreLyrics1Gbo, gbo adura mi; Olorun Oba Olore Gbo ohun ekun mi; Jehova Oba alanu Iwo lo gbo ti Hezekiah Nigbati ojo iku re de2Gbo, gbo majemu mi, Baba omo emi mimo Gbo ohun ebe mi, Oluwa awon Oba Iwo lo ngbo adura Mose gbati Korah ndite si.3Gbo, gbo, ohun ekun mi Olorun eleda mi Majeki nku iku odun yi, gbo ebe mi eleda mi Iwo lo gbo adura Danieli Gbo temi Olorun mi4Wo bi iku ti nta ofa simi, Ipo oku nlanu tı mı Awon omo oso gbogbo gbara Nwon si nwa ikoto fun mi Baba to gbo ekun Dafidi Ma jeki nwo ile lodun yi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryGbo nigbati mo ba npe, Olorun ododo mi Ps. 27:7 Previous282 · Wadi mi Oluwa, wadi miNext 284 · Gbogbo enyin iran Israeli