No. 285Leba odo BabeliLyrics1Leba odo Babeli Nibe la gbe joko Mo si nsokun gba mo ranti Sioni Mo ka ogo aye sofo2Leba odo Jordani Nibe la gbe joko Mo si nsokun gba mo ranti Sioni Mo ka ogo aye sofo3Jeki emi olutunu; Fi oro Sioni han mi Kin ka ogo aye sofo4Oluwa ranti Sioni Lodo omo Edomu Nwon nso lojojumo wipe Wo pale de ipele re Mo ka oro won sofo5Iwo omo obirin Babeli Eniti iparun wa fun Abukun si ni fun iwo Lati pa omu inu re Mo korira ota Olorun6Ninu aginju aye Nibe la gbe joko Mo si nsokun gba mo ranti Sioni Mo ka ogo aye sofo7Ninu aginju Esu Nibe la gbe joko Mo si nsokun Gbati mo ranti Sioni Mo ka ogo aye sofo8Ninu sinagogu aye Nibe la gbe joko Mo si nsokun Gba mo ranti Sioni Nko fi ile won sileAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN ORO PSALM 136 Previous284 · Gbogbo enyin iran IsraeliNext 286 · Mo gbo oro kan lenu obirin