No. 306Igbogun irokekeLyrics1Igbogun irokeke T'awon omolehin Kristi yi ti Siloh o Siloh o yara wa gba wa la2Apata oro edidi Ti awon omolehin Kristi yi ti po o (2x) Olofin o Sion o yara wa gba wa la3Maramahan dalau elo (2x) Mini-salau elo Minisil alau4Ojo duro lori Olofin O duro O duro o Ojo wo o Eri o Baba Eri Eri oAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956ORIN MIMO NI WEDNESDAY 3/12/56 IRO KEKE ATI IGBOGINSimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun Previous305 · Goligota ibi agbariNext 307 · Oba Olupilese igbagbo yara wa