No. 309Ojo simi lojo owoLyrics1Ojo simi lojo owo Ti a o ma fi iyin Oluwa (2x) Gbogbo araye ewa kajo yin Oluwa Ojo simi lojo owo Ti a o ma fi yin Oluwa2Ojo mefa ni Oluwa so Pe ka se ise wa gbogbo Gbogbo araye ewa kajo yin Oluwa Angeli orun e bo, ka korin iyin o Lojo isimi Oluwa3Angeli oniwosan jo sokale Lojo isimi Oluwa (2x) Wa se iwosan wa tokan tara Araye e bo ka korin iyin o Lojo isimi Oluwa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956ORIN MIMO NI SUNDAY 23/12/56Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun Previous308 · Mori keke kan mbo lona ila orunNext 310 · E iba re O misiah Olori omo