No. 311Oluwa ti joba lori oke ZionLyrics1Oluwa ti joba lori oke Zion Oro Kristi gbile lori oke eri Ko si eda to le si Oluwa nipo Lorun ati laye2Olorun ti joba ki abanije to de Oro Siloh gbile ki awon aseke to de Ko si eda to le si Oluwa nipo Lori oke sioni3Olofin ti joba Olanla lo wo laso Oro eri ti de ki alaigbagbo to de Tani le fo apata Kristi to gbe kale fun wa Ko si eni to le se.4Oluwati joba lori Oke Zion Ogunwa lori ite Olanla lo wo laso Ogbon duro lori oke eri O nfun omo re loroAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous310 · E iba re O misiah Olori omoNext 312 · Gbati o wa lominira o