No. 332Gbo orin tawon irawo meje nkoLyrics1Gbo orin tawon irawo meje nko Gbo orin tawon irawo meje nko Nwon nkorin nipa kikun keferi Pe ko le pin, pe ko le pin, lodo Aiye.2Awosama ki kuro lehin Ojo Iro kikun ki dake ninu okun Beni kikun awon keferi Ko le pin, ko le pin, lori Onigbagbo3'Gbawo ni kikun awon keferi yio pin /2times Olorun so pe yio di ehin Arimagedon Ki kikun won ko to dopin li Oluwa nwi.4Lojojumo ni Angeli Olorun nsoro /2times Beni Angeli Lusifar yio ma soro Yio ma soro kikun sairin oloto5Ategun to nfe ko ti duro Isan omi ti nwo ko ti duro Beni kikun awon Keferi Ko le dopin, ko le dopin, lori Onigbagbo.6Nigbati o ba di ojo idajo Oluwa Gbogbo kikun awon keferi yio pin Iro Orin ayo layanfe yio ma gbo Yio ma ba awon oke meje Korin ododoAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo T.H.M.S.A. Previous331 · The Hermmar RomisionallyNext 333 · Ojo aiye to nro lori mi