No. 340Iwa mimo ni ibere SerafuLyrics1Iwa mimo ni ibere Serafu Ihinrere l'afurugbin To ngbe agbelebu.2Mose gbe agbelebu Ni ilu Ikare O rin irin-ajo ihinrere Titi de ilu Eko3Lene gbe agbelebu Ni ilu Erunna O rin irin-ajo ihinrere Titi de Araromi O rin irin-ajo ihinrere De ilu Oghoye4Imole Kristi tan Agbelebu wo inu okan Won nfomije wa igbala Won ri Kristi di mu.5Nwon gba ihinrere Kristi f'onje won Won faiwe je 'rawon niya Won nje mana ninu ala6Asia Serafu nfo Lati ile de ile Agbelebu pada d'ewa Lokan Onihinrere7Gba won wa ninu ala Won ba angeli di ore Gbogbo ohun isogo aiye Sin di irira fun won8Ogo Kristi ndagba Eso igi ajara npon Owo awon Olukore nro Afurugbin ko si9Mase wo ogo aiye Ka egan Kristi soro Aiye ko ladun fun awon To nwo ewa Jesu10Mase siwo ise Titi ile yoo fi sun Oni idajo kan nbo wa Lehin Okunkun aiye11Majoko-Ma duro Rin irin Olorun re Ikore po ko si alagbase Rin irin Olorun re12Jesu Oluwa re Ko duro-ko joko O nkiri nwa awon agutan Se e bi Oun ti se e13Rin irin Olorun re Ma duro-ma joko Eso ajara pon pupo Lo se itoju won14Tire ni Oluwa Mase tiju eri re Dide gbe agbelebu re Mase ka elegan si.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Ikede Oro Jesu Sainary Mennary Alore Jesu C/S Matt 28:18 Previous339 · Tete pada sile reNext 341 · Iri Siloh ti mo ri O