No. 350Eda feran owo ju emi loLyrics1Eda feran owo ju emi lo Eda feran owo ju omo loChorusNwon nfe - Nwon nfe Eda feran owo ju emi lo2Nje owo ti iwo ngbekele Ha le mu won wo ijoba Olorun Iro ni asan ni Owo kole mu ni de oke orun3Oro ti enia fi iwa asan ni Ko le duro laiye ati lorun E soku enyin Oloro Nitoripe osi mbo wa ta yin.4Kilohun ti emi yio se? Temi yio fi de orun rere Nko ni se oso. Ngo je onife rere Gbana lemi yio fi ona orun han mi.5Bi nba je oso ati aje Bi nko laje ti emi ko mo Olorun Inu ina ebi orun apadi Lemi yio gbe ni ipin temi si.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday 21st June 1957 The Hammar Romisionally Previous349 · Nje enia ko ni igbagbo ti e gba o araNext 351 · Mo fi o se Oluso omo mi