No. 356Asotele Siloh ti mo moLyrics1Asotele Siloh ti mo mo Nipe o mbo nibi ipamo Imole nla yio yo ni ikoko Ki gbogbo aiye to ri2Awon Angeli yio korin o ye Adaba yio ta okun oro Awon ogun orun yio ba okun oro bo Egbo ami wiwa Siloh.3Bi enyin tile mo ami won yi E ko le Saitapa si E o sope ilu kekere yi Ni olugbala ti wa?4Igba wiwa Siloh yio soro Fun awon alaigbagbo Nwon nsope ilu kekere yi Ko le ri Olugbala bi.5Wo omobirin to nbi ni ile iso Ko ke pupo ko to bi Alabukun ni fun inu re To gba Olugbala si6Gbogbo Woli ekiyesi ara Ki e le mo igba wiwa na Ki enyin ma ba kose pelu aiye ki e ma ba di iwefa esu.7Gbogbo irawo oju orun rojo po Ogo osupa tele won Itansan ojo si ntele won lo Baba ologo meta de.8NDAU NSAINAH BABA Olore Tani le mo ibu aiye? Baba NDAU TAUSA LAU HERMMAR Omo gba ERi Baba so.9Wo awon Nasiri ni ile iso Nwon wa ninu LAWANI Eku iro lori omo Siloh Enyin ijo Aposteli.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo The Harmmar Halory Previous355 · Oluwa to fi ase iwosanNext 357 · Kini ami wiwa Siloh to mbo