No. 359Bi awa ba duro ninu ife OlorunLyrics1Bi awa ba duro ninu ife Olorun Lehin arimagedon Jerusalem o lawa nlo2Jerusalem iwo to ti oke wa Ayo inu re ko fi ojo kan lopin Ni gbogbo ojo ni3Awon omo oso ati omo aje Yio ma ke oro ninu ina Ti nfi Suferi jo4Ohun ni igbe oro - ohun igbe epa Ni yio je orin - Fun awon alaigbagbo Ni ikehin ojo.5Kristi to ti ku -On si ti ye Bi awa ba gbabo - Awa na yio ku A o si tun ye.6Kristi oluso rere - Nigbati on ku Osi fi eje re ra - awon ayanfe pada Nwon di ominira.7Orin ayo lawa yio ko -Nite Kristi o Bi a ba le se igbagbo de opin Awa na yio ma yo8Iwo apata Alfa Ihinrere omega Olorun Mose o - Rabbi Emmanueli Fi ona orun ha mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday Noon 13/7/57 Orin ayo onigbagbo lehin idajo Arimaged Arinmagedon The harmmar Sainah Halory Previous358 · Orin yato sori ooooNext 360 · Oba rere gba wa o