No. 364Wo ami to han lorunLyrics1Wo ami to han lorun Ojo duro si iwo orun Osupa duro si ila orun Nwon nso igba wiwa omo Siloh2Eje ki a fi inu sokan Ki Siloh le wa sairin wa O mbo bi owara ojo O mbo bi iri Owuro3Gbo bi Angeli ti nkorin ayo Nipa Omo Siloh to mbo Eje ki awa ma sona Ki a le mo igba wiwa siloh.4Baba ti ngbe Siloh ga Ju angeli ati Olofin lo Siloh re ogo re sile O mbo ninu awon Olofin.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Sunday 21/7/57 Orin ayo Omo Siloh T.H.S.H. Previous363 · Olori ijo wa mbe loruNext 365 · Siloh mbo lati mu okunkun aiye kuro