No. 393Wo ilekun titun to si lorunLyrics1Wo ilekun titun to si lorun Ti awon ogun orun duro ti Alore Orun nkorin si mi Pe ki nwa wo agbala Oluwa.2Emi hale wo agbala Oluwa Pelu eran ara ese mi Angeli nsope emi yio ku Emi mi nikan yio lo sorun3Wo bi awon Alore Sioni Ti nduro leba ilekun na Lawani won nfun bi Sno Nwon nkorin Ogo Siloh to mbo4Wara to nsan loke to mbo Gege bi yinyin nla Nigbati oba kan si ara mi Ara mi hale duro gba oro?5Ogo isaju yio kere ju Lara ogo ikehin to mbo Wo bi adaba ati lekeleke Nwon da agbara emi bo sode aiye.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday 5/10/57 T. H. S. A Previous392 · Alilluya Alilluya Alore Sioni mi mboNext 394 · Kristi Oluso Aguntan rere