No. 395Kise emi nikan loyan ara miLyrics1Kise emi nikan loyan ara mi Lati wa si ode aiye /2times Olorun lo se eda mi, o fi mi sinu iya mi Iya mi si robi mi obi mi lase Oluwa2Emi ko mo okan -gbati mo ko de Sori ile aiye /2times Laipe langeli nso fun mi Pe Olorun lo ran mi wa Lati fi ogo orun han fun Gbogbo orile ede aiye.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday 11/10/57 T.H.S.E.A. Previous394 · Kristi Oluso Aguntan rereNext 396 · Emi ko dide fun ibaje ijo lori oke yi