No. 398Ji dide, ji dide, bi awon ara igbaniLyrics1Ji dide, ji dide, bi awon ara igbani /2times Korin ope si Oluwa soro igbala fun enia Ji dide ji dide lati soro ikede2Lo wasu lo si ikede bi awon ara igbani /2times Fi irekoja awon enia han won Fi aisedede elese han Fi ipe senu, fon ipe ihinrere Ke efe ati eke kuro3Ma ka egan si, ma ka esin si Sa soro Olorun re, Bi aiye mbu o sama yo Beni won bu ara igbani Se gege, se gege bi awon ara Igbani4Kede idasile, kede igbala fun awon igbekun Ka gboro Olorun nikan Koro Satani le rele. Gbe Kristi ga Fi ogo Kristi han fun gbogbo orile ede.5Wasu ododo jeri ihinrere bi awon Aposteli Fi imole han awon afoju Fi oye ye alailoye, jeri Kristi Soro ihinrere bi awon ara igbani6Tera mo adura sama gbadura Bi awon akoni igbani Se iwosan fun awon alaisan Jeki iro egbogi rele, bere lowo Olorun Yio fun o lase iwosan7Se gege, se gege, bi awon ayanfe igbani Sa ipa re lati gboro Olorun Mase gboro eko omo esu Se ki a ji dide ki ilekun ma ba ti.8Fi oro mi han, fi ogo mi han fun awon keferi Tesiwaju ma wo ehin Ki gbe aiwe fun elese korin ipe ododo Soro iwasu fun awon alaigbagbe9Torile ede kan (2times) de orile ede omiran Ji gbogbo awon enia to sun Fi ogo Kristi han fun won Ti ileto kan soro ikede de ileto miran.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Tuesday T.H.M.S.A. Previous397 · Tx Exmennah mi o, onsonallNext 399 · Iya Iya lori iya fun o o