No. 402Iwo odo agutan OlorunLyrics1Iwo odo agutan Olorun Eniti yio ko ese araiye lo John ri O ninu emi ori O lojukoju2E be mo mbe Olorun To seda ohun gbogbo Ko jeki nle ri Kristi ninu emi ati ojukoju.3Iwo ti awon Ju mu lo fun pipa To yadi niwaju won O ko se niwaju won pe o ki se omo Olorun4Kristi'gbati o ba kan wa Lati je iya fun o Maje ki nle se O o pe akise omo re5Ade egun to kan o lori Itun ti won tu si oju re Otin kikan ti o mu Fun igbala mi lo gba fun6Sipia to gun o ni iha Esin ti won fi o se Opa iye to kan o lori Nitori mi lo se gba7Kristi to je iya fun mi Laijepe mo san owo fun Ngo ma gbe oruko re ga Ki nje iya tori ogo re.8Bi Kristi ti je iya fun mi Bi mo ba je iya tori oruko re Iya mi hale je ere fun Kristi Mo nje iya tori igbala mi9Woli nitoto ni o Iwo to je iya fun eselese Oru aisedede aiye lo Aiye kori tire ru10Gbogbo alufa to siwaju re Nwon ko fi ara won se etutu Alufa toto ni o Wo to fi ara re se ebo ese11Holy Mennah omo Olorun Wo to ku nitori mi Jeki nku iku ododo re Ki nle nipo lodo re12Kristi ninu ongbe re Emi ko fun o lomi Mase ro ti aisedede mi Jo jeki nri ranlowo re.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Friday 22/11/57 The Hermmar Sainary Alore P. A. W. D Previous401 · How Hermmar Sainary ti ndauNext 403 · Okiki igbogun esu oti po lori ijo Ju o