No. 404Olorun OLuwa mo wa ke pe oLyrics1Olorun OLuwa mo wa ke pe o o /2times Jeki isin wa ojo oni le je itewogba lodo re Olorun Oluwa mo wa ke pe o o2Oba Oluwosan mo gbadura si o Jeki gbogbo alaisan wa le gba iwosan loni Mo mbe o Oba oluwosan mo nkepe o o3Baba oludariji jofi ese wa ji wa Mase ro ti ese ti a nda si o Onda si o, ati si enia Olorun Ran agbara iwosan ko so wa di itura.4Le aisan jina si wa - le esu jina si wa Mase jeki agbara iku le ka wa loke Eri Olorun Toju alakoso ijo - Toju omolehin ijo5Sainu fun Akoni wa sainu fun Woli wa Sainu fun gbogbo awon to gbo ipe lenu Woli Mo mbe o Maje ki aisan de won, maje ki esu bo won6Jeki awosama re ba le gbogbo ijo Ran agbara imo si gbogbo wa Ki esu ma damu wa Olorun Fun wa lasotele lati gbe ijo re ro.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Sunday Morning 24/11/57 Orin isin ojo isinmi T. H. S. A. Previous403 · Okiki igbogun esu oti po lori ijo Ju oNext 405 · Pada iku pada lehin mi