No. 407Bi mo ni ifihan ode araLyrics1Bi mo ni ifihan ode ara Bi nko ni ifihan sinu Emi dabi kimbali To ndun lohun goro Ti ko le nikan soro Laijepe enia lu.2Wo ile wa - Ta towo enikan ko To lewa gidigidi -Bi ile na ti lewa to Ko lonje kankan sinu Ebi pa awon to wo ibe ku.3Ka to joko sipo oye - oye ko logo sinu Ka ma ba dabi kangan Ti ko lomi kan sinu Ti nho iho nho itiju re jade Bi enia ba fe lo bu omi re4Ifihan ti ode ara - ko lere kankan sinu Ko mo otun ko mo osi Ori gege bi igi ope Ta towo olona se Ti won fi iso ati olulu di mu5Eniti o ni ifihan tinu Yio ma soro ogbon sode Gbogbo ijo yio ko eko re Je ka ni ifihan tinu Ka to joko sipo oye Ka ma ba di eleran ara6Baba fi imo osupa Imo ojo ati irawo Sinu mi ko di ifihan Mase jeki eran ara Le gba mi lowo emi Jeki emi nikan to mi o.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Wednesday 29/11/57 The Hermmar Sainary Alore Previous406 · Alilluya Alilluya Ile Herrammar ti deNext 408 · Sunmo Kristi gbe agbelebu