Before you read

No. 413

Olorun soro ni ipilese

Lyrics

Chorus

Ogo Ola iyin agbara Ni fun Olorun loke

Chorus

Ile si hu irugbin jade Ogo ni fun Olorun loke

Chorus

Obinrin si nrobi obi Omo Ogo ni fun Olorun loke

Chorus

Ogo ati agbara ati ipa Ni fun Olorun loke

Chorus

Kabiyesi Ogo ni fun Olanla Olorun loke

Chorus

Iyin Ope ogo Ola Ni fun Olorun loke

Amin

About this hymn

Written by
Prophet Mennary

Orin Mimo ni Sunday Morning 15/12/57 Holy Pretend Mennah The Hermmar Sainary 5% The Hermmar Sainary Alore