No. 418Olorun OlupileseLyrics1Olorun Olupilese Ase re lo fi da mi Ran agbara emi re si mi Ko le mu mi wo ile re2Ongbe emi re ngbe mi Ara ni mi tori re Ro ojo emi re sori mi Jeki iri emi wo inu mi3Wo awon onigbagbo apakan Ti nfi oju ifehan lode Nwon nfi oju aigbagbo sinu Nwon fe nrin ogo re mole4Wo ona meji lode aiye Ewo lemi o tele? Je ki emi re bale mi Ko le fi ona re han mi5Olorun Olumo okan O mo gbogbo ese mi Ikan ko pamo loju e Je ki ngbagbo ju ese mi lo6O ran emi resi awon ara igbani Ni won ba mo ona oto re Ran emi amona simi Ki o le fi ona han mi7Mimo Mimo ni Olorun Eleda aiye ati Orun Mu ki emi re bale mi Ko le mu mi gba o gbo8Wo pupo awon to jewo re Lori oke ERI ZION Ti nfoju igbagbo sode Nwon nfoju arakan sinu9Kristi to mi loke ERI Toju ogo re to fifun mi Maje ki aiye fi etan gba ogo mi Fi emi re to mi dagba.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Thursday 19/12/57 Holy Pretend Mennah 10% The Hermmar Sainary Alore Previous417 · Iri ibukun lemi ntoroNext 419 · Gbogbo awon Alore to duro