No. 420Olorun iwo ni Eleda miLyrics1Olorun iwo ni Eleda mi Iwo ni Eleda-Awon Angel mimo re Iwo da awon Angel ni pipe Kini se tofi dami pelu abaiwon2Bi ojo ti ntobi to ni Agbara re nikan, lo fi nda kiri Emi to kere bi era niwaju re Kini se to ko fi agbara re to mi3Olorun iwo loba awon Oba Kristi lo bori gbogbo awon ijoye Iwo ni Oluwa awon Oluwa Sama fi apa mimo re nikan to mi4Gbogbo Oba aiye yi lo nseke Iwo nikan li Oba ti ki seke Gbogbo Oba aiye yi yio ku Iwo nikan loba ti ki ku5Olorun iwo lemi nse loba Emi o yin o larin ijo mimo Emi o ma rohin oruko mimo re Ki nba le ri aiku gba lodo re6Gbogbo awon tinfi etan sin Olorun Ina ebi orun apadi yio fi etan su won Titi won o di itemole fun awon oloto7Gbogbo awon Alore to duro Nwon fi iwa pipe sin Olorun Gbogbo awa akorin isisiyi Eje ka ko iwa pipe lodo orin ta ngbo8Kilohun ti emi yio se? Ti emi yio fi kuro ninu ete eke Kilohun ti emi yio se Temi yio fi kuro ninu ika siso9Olorun jo le eke fun mi Jeki so otito re titi de oju iku Fi agbara emi re wo mi Bi mo ti nfi aso wo ara mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Saturday Night 28/12/57 Holy Pretend Mininah 13% Melo Melo fasainnary Dau Sauh The Hermmar Sainary Alore Previous419 · Gbogbo awon Alore to duroNext 421 · Wiri wiri Wiri wiri