No. 427Geography orun ti Olorun fifun waLyrics1Geography orun ti Olorun fifun wa Hygiene orun ti Olorun fifun wa O ye ka ma lo o oye kama lo o2Imototo alore ti Olorun fi funwa Eri to mo gara ti Olorun fifun wa O ye ka ma lo o oye ka ma loo3Sainary igbagbo ti Olorun fifun wa Ami alore orun ti Olorun fifun wa O ye ka ma loo oye ka ma loo4Nigbati awa tigba sainary alore Koye ki a tun fi ara wa yi eri mo O ye ka sora o O ye ka sora o.5Funfun gbo ni oro Olodumare Oye fun onigbagbo lati funfun laulau Eje ki a gbagbo ka le di mimo o6O ye fun awon akorin lati lo imototo O ye fun gbogbo ijo lati ni geography O ye ki ara wa mo o oye ki inu wa mo o7E je ki a dupe lowo Olorun eleda To fi iri alore se ewa si wa lara Eje ki a wole o Teriba fun Olorun.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo ni Tuesday Morning 3/2/59 - I. C. O 8 Previous426 · Arole ni o o AloreNext 428 · Wo bi isan omi aiye ti ngbe mi