
No. 433
Rori mi wundia Isreali e
Lyrics
Amin
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
Orin Mimo ni Monday Evening 27/4/59 I. C. O. 8
Mori igbi nla kan ga pupo to be kosi eda to le rekoja lori re Mori adaba kan na apalori igbi ha mori awa enia ile yi duro koju si igbi na ni apa ila orun-bi igbi na ti mura lati ye pupo enia beresi subu lule-nigba na ni Adaba na nkorin bayi pe: - Rori mi o Wundia, Isreali no-