No. 439Iwo Alore HermmarLyrics1Iwo Alore Hermmar Feti orun fun mi Ki nle fi ma gboro Orun ju taiye lo Oro Orun ni mo ntoro Iri Orun ni mo mbere Eko Orun ni mo ntoro lodo re Baba.2Iwo Angeli Olorun Fi iran orun han mi Ki emi ba le mona Lati sin Olorun Iran Orun ni mo ntoro Ase Olorun ni mo ntoro Ogo emi ni mo nbere lodo baba3Mo wa ninu ago aiye Mo nke irora Ngo fe ki nke irora-lagbala Baba Ko si ere kan laiye - aiye yi yio di ofo Baba jeki nleri ona-bale wole Ogo re4Bi mo ti ngbo oro Olorun Nko fe dese mo Mo mope ase Olorun ni Nko gbodo yipada Sugbon bi mo dele mi Tabi bi mo wa lode Lesu ran iko re si mi Ko le mu mi dese.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous438 · Oh be slow Oh be slowNext 440 · Okan mi jeri si Iyin Olorun