No. 449Okan mi mase padaLyrics1Okan mi mase pada Kuro nise Aposteli Aiya mi mase yipada Kuro ninu ofin Christ2Iwa mi mase pada Kuro ni ise ilu eri Okan mi mase yipada Kuro ni ijosin re3Ninu Ihinrere Ologo to gba Lori oke eri Zion Ki e mase wo iwa ibi enia Ki a to gba Christi gbo.4E ma se ro ti ibaje enia Ninu igbagbo tia gba Bi a ba fe ro ti ibaje enia A ko le se igbagbo na.5Kristi Oluwa ti awa nsin Ko se wa ni ibi kan E mase tori ibaje enia Se si Oluwa Olorun.6Ise iye meji ni ewu pupo Fun awon to mo Olorun Iyipada Onigbagbo Yio bo si ewu iponju.7Gbo oro Oluwa iwo okan mi Gbo oro Olorun iwo aiya mi Ki e mase dami kuro Ninu isin Ologo yi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous448 · Gbati enia ba wa ninu emiNext 450 · Iwo ta wosan ninu aisan re