No. 455Sile kun Ododo sileLyrics1Sile kun Ododo sile Fun mi Oluwa mi Je kinle ri ona ba wole Ogo Re Silekun ododo sile fun mi2Fo idoti oju mi kuro Ki nle ri ona ogo Re Ki nba le ri ona lati tele O Fo idoti oju mi kuro3Igbimopo aiye ndaru Nko mo eyiti ngo se Jo fo odi orisa tin be lokan mi Kuro Silekun ododo sile fun mi4Iran didan ni emi ntoro Lodo Olorun mi Fun mi ni agbara aiwe ati agbara adura Ki nle fi segun esu ati ese5Baba mi iri re bale mi Fun mi lopo irin Kinle fima sakoso larin orile ede Ki gbogbo aiye lemo iwo nikan6Olorun nlo ipa lode aiye Dragoni si nru ipa na Olorun eleda mi eleda gbogbo woli Jo ti odo ijosin yi se apa satani.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous454 · Jerusalem ti Orun ti de oNext 456 · Oye ki a fi apata pipe ti a gba