No. 457Bi Olorun tinbe nibi gbogbo laiyeLyrics1Bi Olorun tinbe nibi gbogbo laiye Beni esu si wa nibi gbogbo laiye Ha Olorun eleda mi jogba mi2Mo tori esu mo sa fun ile mi Mo tun pade esu lode Ha Olorun Olodumare Jo so mi.3Eke po ninu ijosin aiye To ri be mo se kuro nibe Mo pada sinu Ijo Aposteli Mo tun ri eke arakunrin.4Ha Olorun nibo lemi yio lo Ti emi yio ri eniti okan mi fe Ti emi ati on yio ma yin O Ni iwa mimo.5Pupo awon enia to ba mi nwo ile re Nwon wa fun eke ati ami sise Nwon kotile wafun ilosiwaju ijo Bikose iyan jija.6Krist gbami lowo eke arakunrin Ati lowo eke arabirin Maje ki nsubu si owo esu Olorun eleda mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous456 · Oye ki a fi apata pipe ti a gbaNext 458 · A de Oba eri lere