No. 467Wo odo Mimo to mo garaLyrics1Wo odo Mimo to mo gara Ti Olorun mu mi ri Nibe ni awon asaju wa So erun won kale2Ki won to de odo na Nwon ti gba ami Kristi Oruko odo aguntan Si mbe niwaju won3Ona ewo lemi yio gba? De odo didan na Ti emi yi o so erun mi kale Bi awon ara igbani.4Wo ogiri ese Ti esu fi ndi ona mi Ti ko jeki nle rin ona Olorun ni gara5Ipe Aiye to ndun ni Ti.awon enia nsare si Ewa ati irera aiye Yio bo si ebi orun6Ipe duru aiye Ipe fere aiye Olorun eleda mi Maje ki nsare si7Ipe ogo ipe pipe Lati odo re lo ti wa Fi ipe ihinrere Mu aiya mi bale8Ebe mo mbe Baba Ko fi e ase re si ete mi Ko fi ogo kun ara mi Ki nle gbe ago Ogo Re.9Yipada si awon agan Ko fun won lomo bi Fi agbara emi idande re Gba mi lowo esu.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous466 · Tani ni ago wura to sonu oNext 468 · Alleluyah Alleluyah Awa ni ile Olorun