No. 475Nigbawo ni emi o ri O Olorun miLyrics1Nigbawo ni emi o ri O Olorun mi? Nigbawo ni emi o ri O Olorun mi?2Mo hale ri O pelu eke Olorun mi Emi nsope ngo ri Olorun Pelu, okan mimo3Lojojumo l'anri Olorun Ninu emi Sugbon emi ki iba ara gbe Titi lailai4Oluwa mi mbe lodo mi Bi akoni Ologun Emi o ma jo emi o ma yo ninu Oluwa5Gbati iyepe ba di erupe ti emi ba yi si Ogo ngo ri Oluwa lori ite Re ngo makorin iyin6Olorun Aburahamu Olorun Isreali mase fi mi sile Sa gbe inu mi soro Ododo Fi ona Orun han mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous474 · Mofi Okan ati ara mi fun OlorunNext 476 · Olorun mi sanu funmi