No. 503O ye ki awa dupeLyrics1O ye ki awa dupe Tori Ore gbogbo Ti Olorun nse fun wa Lati ojo de ojo2Pupo awon Oba Lo nfe ri Ojo oni Sugbon iku ko gba fun won Won di eni erupe3Pupo awon enia Lo nsagbe ko to jeun Sugbon ti wa ko ribe Olorun lo nbo wa4Pupo awon enia Lo fi Orisa ba ara je Sugbon Olorun fara han wa Loke eri ihin5Duru Olorun nfon Orin ALore nso Olorun yi eti wa si O nlo ahon wa si.6Gbogbo enyin Omo Alore To nse apon nisisiyi E mase ba ara nyin je Ki e le di wundia7Olorun eleda wa O tun ti ara wa nya eya O fun wa loruko mimo Ti awa o ma pe won.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous502 · Alau dahau HermmarNext 504 · Jeki nle ri oju re