No. 51 · Orin AsoteleMo gbọ ọrọ edidi ọrun Lyrics1Mo gbọ ọrọ edidi ọrun (2ce.) To nsọ nipa ọmọ siloh Mo ngbọ ọrọ olofin ọrun2Olofin ọrun nsọ si mi pe A o tipa woli bimọ Nibiti aiye ko fi oju si.3Mo ri ọmọ kekere kan To njade nibi ẹgun aiye Onigbagbọ yio tapa si.4Ẹgun pọ nibi ibimọ yi (2ce.) Pupọ Onigbagbọ yio kọsẹ Lọna ti Siloh gba mbọ yi.5Aiye pese ọna fun Siloh (2ce.) Siloh kọ rin ọna taiye ṣe Ọna ti Baba lo fẹ nrin.6Ọna aiye dara loju aiye Ko dara loju Ọlọrun Tori bẹ Siloh ko le gba.7Tani iwọ bi awọsanma (2ce.) To duro lori ọmọbinrin O tun pada sọdọ Woli.8Gbogbo eyin Nasareti wa (2x) Jeka duro ninu ogbon Nipa omo siloh ti nbo yi9Tani iwo bi iri owara ojo Tani iwo bi iri owuro To mu okan Woli kun fun oro To rin ona egan aye nbo10Siloh nbo lona egan aye Nibiti aye yo pa ose si Nibe ni siloh yo ti de11Siloh nbo inu aye baje Gbogbo won nsoro bururu Pe ona siloh gba ko dara12Emi Siloh lo ran omo mi Lati so oro yi fun yin E ma se si iranse mi gboAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORIN EMI OLUWA NKỌNIComposed Friday night 30 November 1957. Similar hymns119Wo Woli Siloh to ti Judiah sọkalẹ1958 · Orin Asotele186Ọlọrun yan mi si woliOrin Asotele188Korin ogo silohOrin Asotele155Lori oke Rama - lori oke asotele1957 · Orin Asotele Previous50 · Awon wo lawon wonyiNext 52 · Ihinrere Jesu: Ise yanu Lenę