No. 512Oluwa mi ma- se sa mi tiLyrics1Oluwa mi ma- se sa mi ti Kuro niwaju Ogo Re Bi oko ti nfa Iyawo Re mora Beni ki o fa mora.2Fi emi irele Re wo mi Ki nle ko oju Ija si esu Mase jeki nle tele esu Se buburu ti on nse.3Ogo pipe Re to fun mi Mase gba kuro lodo mi So Ofin siloh mo aiya mi Ki nma bale se O.4Alore re ba mi nrojo Ko si are mi ninu ejo na Tori be mo re ara mi sile Mo nbe O gbe mi ga5Omu wundia odo Re Lemi fef ma mu lojojo Omi ti awon ayanfe mu Ti won jogun iye6Oluwa jo fi enu ko mi lenu Mase pa Oju Re mo fun mi Oba mi wi tori aisedede Mase fi mi sile fun iku7Da aiya titun sinu Okan Mi Fi emi alore Re gbe mi ro Fi apa mi se apa igbala Re Toju mi labe lye Re8Oluwa mi fi apa emi bomi Bi agbebo aiye ti nse Omo Re Gba mi lowo Jigbesan ese Ko mi ni ilana.9Fi Omu Wundia Re to mi Fi Opa Omo Jesse nikan to mi Mase jeki emi esu to mi Mo fi ara mi fun O10Mase wu mi bi o ti wu esu Kuro lori Oke mimo Re. Mase gba Ogo Re kuro lodo mi Toju mi leba Ogo Re.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous511 · Yin, yin, yin-yin Olorun eleda reNext 513 · Iwo Adaba Mennah