No. 515Ngo duro si Pentcost ti emiLyrics1Ngo duro si Pentcost ti emi Nibe ni Idande wa Ngo ro si pentcost ti emi Nibe ni itura mi wa.2Baba wo bi awon elese Ti nyipada si O Ma-e doju ti awon elese To yipada nsin O3Gba mi lowo ebi ese Olorun Oba mi We mi kuro ninu ese Ati aisedede mi.4Ilu elese yipada nsin O Oluwa Oba mi Ma se doju Igbagbo ti Awa to wa sin O5Ilu Ninefe yipada sin O Iwo gbo ebe won Awa omo Zion eri npe O Gbo ebe adura wa6Jeki awa elese mo ona Re Mase yadi si wa Jeki adura wa to O lo Gegebi ebe Mose7Gbogbo awa enia gbara jo Lati te duru Orin yin O Jeki awa le ri anu gba Lehin Orin wa yi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Previous514 · Olorun Olufi ori tiNext 516 · Iwo Sioni Ori Oke Olorun