
No. 518
Wo awon to ti Sion jade
Lyrics
Chorus
Ni Oluwa yio mu kuro Gba won ti se Salemu Nwon yio segbe pelu aiye.
Chorus
To nkegan Olorun Eniti o fi egan ba oruko Kristi Ni Olorun yio fi egan ba.
Chorus
Nwon nse ijewo pe Nwon ki se ara wa A! abuku won ni nse.
Chorus
Olorun binu Ati oro isokiso Eyipada enyin omo apehinda Sodo Olorun eleda nyin.
Chorus
Larin ijo ati awon Onigbagbo Won ko gbona won ko tutu Nwon nhuwa Judasi
Chorus
Eni na ni OLorun yio bi subu Bi o ti bi esu subu Kuro larin awon enia re.
Amin
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
Orin Mimo Sainary Alore