No. 525Bi o ba fe lo mi o OlorunLyrics1Bi o bafe lo mi o Olorun 2ce Mase lo mi si ona ti ko pe Bi o ba fe lo mi o Olorun Mase lo mi si ona ti ko ye2Bi o ba fe lo mi o Olorun Fi agbara emi re wo mi Ki nle se bi ara igbani Ki nle sogo loruko re3Bi o ba fe lo mi o Olorun Ti Odo mi se iwosan awon alaisan Bi o ba fe lo mi o Olorun Loruko Re ki nji oku dide.4Bi o ba fe lo mi o Olorun Mase fi emi gerele lo mi Lo mi bi akoni to muna Ki nle fi Ogo Re han araiye5Bi o ba fi iran fun mi ri o Olorun Fi gbogbo ara mi se digi Ki nri iran aiye ati ti Orun Ki aiye le foribale fun o6Maje ki nji emi re lo o Olorun Fi emi mimo Re wo mi Ki emi Re le ju ese mi lo Ki eru ese ma ba pa mi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Sainary Alore Ni Sunday E V. S: 31:5:64 T.F.H.C.F.A.B.H.W. Previous524 · Mo gbo ohun kan to nso loke mi oNext 526 · Mose gun ori oke lo gba ofin