No. 548Mase fi mi sile lo o Ore miLyrics1Mase fi mi sile lo o Ore mi Bi o fi mi sile lo oju a ro mi-o Mase fi mi sile lo ore2Iwo lo nba mi sun losan loru Iwo lo njimi dide ninu oju orunmi Mase fi mi sile lo o ore3Iwo loluso mi ninu iya mi O wa pelu mi gbati Iya mi nro bi mi. Owa pelu mi gbati iya mi bimi Mase fi mi sile lo o ore.4Iwo lo mu mi soro gbati nko le soro . Iwo, lo mu mi riran gbati nko le riran Mase fi mi sile lo o ore5Bi iwo ba fimi sile emi yio di oku Bi o jade lara mi emi yio di ofo Mase fi mi sile lo o ore6Mase fi mi sile lo Adaba mi Kristi Olugbala iwo l'ore mi Iwo sama gbe inu mi emi yio gbe inu re Jowo fi apa re gba mi o olufe.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryOrin Mimo Lona Igbekun I. C. O. S Previous547 · Eli o Omo SionNext 549 · Mo fi adura mi sibi ikoko