No. 85 · Orin Iwa Mimọ · Orin Sioni ati IjọNitori Oluwa mo fi ile mi silẹLyrics1Nitori Oluwa mo fi ile mi silẹ Nitori tirẹ mo fi ọna mi silẹ O Baba, O Baba, mașe kọmi silẹ2Wo ọpọ irawọ, ti nforibalẹ Fun ogo oșupa Wo ọpọ enia ti nforibalẹ fun ogo oke Ẹri O Baba, O Baba, majẹki emi di odi.3Wo ọpọ enia ti nforibalẹ Fun ogo oke Ẹri Wo ọpọ enia nrọ gun ori oke Sioni Ẹri E o Baba, jọ o Baba Ba mi sọrọ ogo.4Wo ọpọ enia ti nfori balẹ fun ogo oke Ẹri Wo ọpọ enia ti nfori balẹ ni wakati rẹ Jọ o Baba (2ce.) bami sọrọ ogo5Wo ọpọ enia ti nrọ gun ori oke Zion Ẹri Wo ọpọ irawọ ti nforibale fun ogo oșupa Jọ o Baba, Jọ o Baba, majẹki emi do fo6Wo awọn Adaba ẹri, ti nra loke Hermar ori mi (2 ce.) Wa o Malo, wa o Malo Sọkalẹ lo ni.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ11Jerusalemu tọrun ti de oOrin Sioni ati Ijọ Previous84 · Kini mo șe yin, ti ẹ fi npokiki mi ? (2 times)Next 86 · Mo gbe ori mi le Ọ Oluwa