No. 91 · Orin Iyin ati ỌpẹJesu l'oluşọ agutan miLyrics1Jesu l'oluşọ agutan mi Ore ẹniti ki ye lailai Ko si ewu bi mo jẹ tirẹ T On si jẹ temi titi.2Nibi odo omi iye nşan Nibẹ ni o nmu ọkan mi lọ Nibiti oko tutu nhu Lo nfi onjẹ ọrun bo mi3Mo ti fi were şako lọ Ni ifẹ Baba o wa mi ri Le jika rẹ lo gbẹ mi si O fi ayọ mu mi lọ ile.4Nko bẹru ojiji iku Bi Baba ba wa lọdọ mi Ọgọ rẹ ati ọpa rẹ Awọn lo ntu ọkan mi lara.5Nwọn si ntẹ tabili fun mi Nwọn si da ororo sori mi A! Ayọ na ha ti pọ to? Ti nti ọdọ Baba wa ba mi.6Bẹ lọjọ aiye mi gbogbo Ore rẹ ki yio yẹ lailai Oluşọ-Agutan ngo yin Ọ Ninu ile rẹ titi lailai.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns138Olorun OlodumareOrin Iyin ati Ọpẹ22Kristi jọba AleluyaOrin Iyin ati Ọpẹ178Oju Mennah mi, oju Adaba miOrin Iyin ati Ọpẹ112Oju Kristi ni oju Adaba miOrin Iyin ati Ọpẹ Previous90 · Ọna kan lo tọka si ọrunNext 92 · Gbati mo wa ninu ẹmi Oluwa